Ipa Orin Ninu Ipolongo Idibo Agbeyewo Ipinle

Student: Moyinoluwa Kemisola Buluro (Project, 2025)
Department of Linguistics and Nigeria Language
Olabisi Onabanjo University, Ago-Iwoye, Ogun State


Abstract

Yorùbá bọ̀!, wọ̀?n ní ajá tó ń gbó ní ohun tó ri tí í fi ń gbo. Ohun tí ó fa ọ̀!rọ̀! yìí ni pé iṣẹ́?ìwádìí yìí ò lè wáyé bí kò bá sí ohun tí ó gún wa ní kẹ́?ṣẹ́? láti ṣe àgbéyẹ́!wò ipa tí orin ń kó nínúètò ìpolongo ìdìbò láwùjọ̀ Yorùbá pàápàá jùlọ̀ ní ìpínlẹ́! Ògùn.Iṣẹ́? ìwádìí yìí yóò fi han gbogbo ayé ipa tí orin ń kó nínú ètò òṣèlú lásìkò tí ìdìbò bá ń bọ̀!lọ̀?nà tí àwọ̀n obìnrin aláfẹ́? olóṣèlú bá ń wá bí iyọ̀! yóò ṣe dun ọ̀bẹ́! ti ẹ́gbẹ́? wọ̀n àní bí wọ̀n yóò ṣejáwé olúborí. Gẹ́?gẹ́? bí ó ṣe hàn pé orin jẹ́? ọ̀!kan lára ohun tí ó máa ń mú òṣèlú dùn, bẹ́?ẹ́! náà ni ójẹ́? pé orin yìí kan náà ni ó máa ń mú òṣèlú le nítorí lákọ̀lákọ̀ ni orin yóò máa bọ̀? lẹ́?nu takọ̀tabolásìkò ìwọ̀?de òṣèlú.Iṣẹ́? apohùn ti wà ní àwùjọ̀ Yorùbá láti ọ̀jọ̀? tó ti pẹ́?, àwọ̀n apohùn yìí á sì máa fi iṣẹ́? wọ̀ndá àwùjọ̀ lárayá, ṣe ìfẹ́!hónúhàn, sọ̀ nípa àwọ̀n ìṣẹ́!lẹ́! àwùjọ̀ mìiràn, ṣe ìdánilẹ́?kọ̀!ọ̀? àti tún àwùjọ̀ ṣe.Wọ̀?n ń fi orin gbé èrò inú wọ̀n jáde pẹ́!lú ohùn dídùn lọ̀?nà tí ó lè gbà wú ni lórí tàbí mú ni lọ̀?kàn.A ṣe àkíyèsí pé irúfẹ́? iṣẹ́? báyìí náà ni orin òṣèlú máa ń fi iṣẹ́? rẹ́! jẹ́? fún ẹ́!dá àwùjọ̀. Èyí ló fún wa niìwúrí àti ìfẹ́? láti ṣe àfihàn rẹ́! láwùjọ̀ akáda gẹ́?gẹ́? bí ọ̀!kan lára oríṣìí orin kan ní ilẹ́! Yorùbá.

Keywords
ipolongo idibo agbeyewo ipinle