Àmúlò Ewì Àti Orin Fún Kíkọ́ Èdè Yorùbá Ní Ilé-Ẹ̀kọ́ Girama Onípele Mẹ́ta Àkọ́kọ́ Ní Ìjọba Ìbílẹ̀ Bórípẹ́, Ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun
Student: SULIYAT OLUWATOBI OGUNLOWO (Project, 2025)
Department of Education and Yoruba
Ekiti State University, Ado-Ekiti, Ekiti State
Abstract
Iṣẹ́ yìí dá lórí “Àmúlò Ewì Orin fún kíkọ́ Èdè Yorùbá ní Ilé-ẹ̀kọ́ Girama Onípele Mẹ́ta Àkọ́kọ́ ní Ìjọba Ìbílẹ̀ Borípẹ́ ní Ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun”. Ewì àti Orin jẹ́ ara ẹ̀yà lítíréṣọ̀ alohùn tí ó lè ṣe ìrànlọ́wọ́ fún ìmúdàgbà-sókè ìmọ̀ àwọn akẹ́kọ̀ọ́ ilé-ẹ̀kọ́ girama tí wọ́ bá ṣe àmúlò wọn dáradára. Ṣùgbọ́n ṣá, ohun tí ó yà wá lẹ́nu ni wí pé àwọn olùkọ́ àti akẹ́kọ̀ọ́ àti akẹ́kọ̀ọ́ èdè Yorùbá kò kọbi ara sí kíkọ́ àwọn abala wọ̀nyìí, èyí ni a sì kíyèsí pé ó ń mú ìfàsẹ́yìn dé bá ìgbélárugẹ abala lítíréṣọ̀ alohùn náà, ìdí sì nìyí tí a fi dágbá lé ìṣẹ́ yìí. Ẹ̀wẹ̀, ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn akẹ́kọ́ọ̀ èdè Yorùbá òde oní ni kò mọ ohun tí a ń pè ní ewì, tí ó sì jẹ́ wí pé orin tí wọ́n mọ̀ kò ju orin tàkasúfé lọ. Èyí jẹ́ ìfàsẹ́yìn ńlá fún ẹ̀kọ́ èdè Yorùbá. Bí a kò bá sì tètè pèèkan ìrókò yìí láti kékeré, apá lè má káa mọ́ tí ó bá yá. Ọgbọ́n ìwádìí tí a lò fún iṣẹ́ yìí jùlọ ni ìfọ̀rọ̀wánilẹ́nuwò láti ọ̀dọ̀ àwọn abẹ́nà ìmọ̀ láwùjọ tí ó mọ̀ nípa ewì àti orin, bákan náà ni a tún lo ìwé iléwọ́ oníbéérè tí a pín fún àwọn akẹ́kọ̀ọ́ láti kó ìmọ̀ jọ. Àbájáde ìṣẹ́ yìí jẹ́ kí a mọ̀ wí pé pàtàkì ni ewì àti orin láti fi kọ́ àwọn akẹ́kọ́ọ̀ ní èdè Yorùbá láwọn ilé-ẹ̀kọ́ girama onípelé mẹ́ta àkọ́kọ̀ọ́.
Keywords
For the full publication, please contact the author directly at: ogunlowosuliyat2@gmail.com
Filters
Institutions
- Novena University, Ogume, Delta State 1
- Nuhu Bamalli Polytechnic, Zaria, Kaduna State 7
- Nwafor Orizu College of Education, Nsugbe, Anambra State 1
- Obafemi Awolowo University, Ile-Ife, Osun State 15
- Oduduwa University, Ipetumodu, Osun State 9
- Ogun State College of Health Technology, Ilese-Ijebu, Ogun State 1
- Ogun State Institute of Tech(formerly Gateway Ict Poly), Igbesa, Ogun State 4
- Olabisi Onabanjo University, Ago-Iwoye, Ogun State 38
- Ondo State University of Medical Sciences, Laje Road, Ondo, Ondo State 1
- Osun State College of Education, Ila-Orangun 1