Àmúlò Ewì Àti Orin Fún Kíkọ́ Èdè Yorùbá Ní Ilé-Ẹ̀kọ́ Girama Onípele Mẹ́ta Àkọ́kọ́ Ní Ìjọba Ìbílẹ̀ Bórípẹ́, Ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun
Student: SULIYAT OLUWATOBI OGUNLOWO (Project, 2025)
Department of Education and Yoruba
Ekiti State University, Ado-Ekiti, Ekiti State
Abstract
Iṣẹ́ yìí dá lórí “Àmúlò Ewì Orin fún kíkọ́ Èdè Yorùbá ní Ilé-ẹ̀kọ́ Girama Onípele Mẹ́ta Àkọ́kọ́ ní Ìjọba Ìbílẹ̀ Borípẹ́ ní Ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun”. Ewì àti Orin jẹ́ ara ẹ̀yà lítíréṣọ̀ alohùn tí ó lè ṣe ìrànlọ́wọ́ fún ìmúdàgbà-sókè ìmọ̀ àwọn akẹ́kọ̀ọ́ ilé-ẹ̀kọ́ girama tí wọ́ bá ṣe àmúlò wọn dáradára. Ṣùgbọ́n ṣá, ohun tí ó yà wá lẹ́nu ni wí pé àwọn olùkọ́ àti akẹ́kọ̀ọ́ àti akẹ́kọ̀ọ́ èdè Yorùbá kò kọbi ara sí kíkọ́ àwọn abala wọ̀nyìí, èyí ni a sì kíyèsí pé ó ń mú ìfàsẹ́yìn dé bá ìgbélárugẹ abala lítíréṣọ̀ alohùn náà, ìdí sì nìyí tí a fi dágbá lé ìṣẹ́ yìí. Ẹ̀wẹ̀, ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn akẹ́kọ́ọ̀ èdè Yorùbá òde oní ni kò mọ ohun tí a ń pè ní ewì, tí ó sì jẹ́ wí pé orin tí wọ́n mọ̀ kò ju orin tàkasúfé lọ. Èyí jẹ́ ìfàsẹ́yìn ńlá fún ẹ̀kọ́ èdè Yorùbá. Bí a kò bá sì tètè pèèkan ìrókò yìí láti kékeré, apá lè má káa mọ́ tí ó bá yá. Ọgbọ́n ìwádìí tí a lò fún iṣẹ́ yìí jùlọ ni ìfọ̀rọ̀wánilẹ́nuwò láti ọ̀dọ̀ àwọn abẹ́nà ìmọ̀ láwùjọ tí ó mọ̀ nípa ewì àti orin, bákan náà ni a tún lo ìwé iléwọ́ oníbéérè tí a pín fún àwọn akẹ́kọ̀ọ́ láti kó ìmọ̀ jọ. Àbájáde ìṣẹ́ yìí jẹ́ kí a mọ̀ wí pé pàtàkì ni ewì àti orin láti fi kọ́ àwọn akẹ́kọ́ọ̀ ní èdè Yorùbá láwọn ilé-ẹ̀kọ́ girama onípelé mẹ́ta àkọ́kọ̀ọ́.
Keywords
For the full publication, please contact the author directly at: ogunlowosuliyat2@gmail.com
Filters
Institutions
- AVE-MARIA UNIVERSITY, PIYANKO, NASARAWA STATE 1
- Babcock University, Ilishan-Remo, Ogun State 7
- Bamidele Olumilua University of Edu. Science and Tech. Ikere Ekiti, Ekiti State 455
- Bauchi State College of Agriculture, Bauchi, Bauchi State 1
- Bauchi State University, Gadau, Bauchi State 16
- Bayelsa State Polytechnic, Aleibiri, Bayelsa State 13
- Bayero University, Kano, Kano State 590
- Benue State Polytechnic, Ugbokolo, Benue State 10
- Benue State University, Makurdi, Benue State 47
- Bingham University, Karu, Nasarawa State 3