Atupale Iwe Ere Onitan Ore Mi Ti Moronmubo Martina Aderibigbe Ko
Student: Fatunmise Adewumi Abe (Project, 2025)
Department of
Ekiti State University, Ado-Ekiti, Ekiti State
Abstract
Awon Yoruba bo, won ni, "mowafoniwa ni jorejore." Iwe ere onitan "ORE MI" da lori omobinrin akekoo ile eko giga fasiti Afonja ti oruko re n je, Solayide, ti obi re ko ni owo lowo sugbon won n gbiyanju fun un. Iwa omoluwabi ni Sola wu titi ti o fi pari eko re. Nje iwa naa so eso rere fun un? Sola pade ore koriko sun kan ninu ile eko giga ti oruko re n je, Kunbi. Iwa won yato gedengbe, won si ni ife ara won. Sugbon se oko ore won gunle si ebute to dara? Kunbi dale ore, igbeyin re ko si dara.
Keywords
For the full publication, please contact the author directly at: fatunmiseadewumi@gmail.com
Filters
Institutions
- Abdul-Gusau Polytechnic, Talata-Mafara, Zamfara State 3
- Abia State Polytechnic, Aba, Abia State 24
- Abia State University, Uturu, Abia State 71
- Abraham Adesanya Polytechnic, Ijebu-Igbo, Ogun State 3
- Abubakar Tafawa Balewa University, Bauchi, Bauchi State 15
- Abubakar Tatari Ali Polytechnic, Bauchi State. (affiliated To Atbu Bauchi) 1
- Achievers University, Owo, Ondo State 6
- Adamawa State University, Mubi, Adamawa State 8
- Adekunle Ajasin University, Akungba-Akoko, Ondo State 26
- Adeleke University, Ede, Osun State 1