Atupale Iwe Ere Onitan Ore Mi Ti Moronmubo Martina Aderibigbe Ko
Student: Fatunmise Adewumi Abe (Project, 2025)
Department of
Ekiti State University, Ado-Ekiti, Ekiti State
Abstract
Awon Yoruba bo, won ni, "mowafoniwa ni jorejore." Iwe ere onitan "ORE MI" da lori omobinrin akekoo ile eko giga fasiti Afonja ti oruko re n je, Solayide, ti obi re ko ni owo lowo sugbon won n gbiyanju fun un. Iwa omoluwabi ni Sola wu titi ti o fi pari eko re. Nje iwa naa so eso rere fun un? Sola pade ore koriko sun kan ninu ile eko giga ti oruko re n je, Kunbi. Iwa won yato gedengbe, won si ni ife ara won. Sugbon se oko ore won gunle si ebute to dara? Kunbi dale ore, igbeyin re ko si dara.
Keywords
For the full publication, please contact the author directly at: fatunmiseadewumi@gmail.com
Filters
Institutions
- Federal University of Technology, Minna, Niger State 47
- Federal University of Technology, Owerri, Imo State 95
- Federal University Oye-Ekiti, Ekiti State 41
- Federal University, Birnin-Kebbi, Kebbi State 37
- Federal University, Dutse, Jigawa State 6
- Federal University, Dutsin-Ma, Katsina State 63
- Federal University, Gashua, Yobe State 3
- Federal University, Gusau, Zamfara State 14
- Federal University, Kashere, Gombe State 1
- Federal University, Lafia, Nasarawa State 6