Atupale Iwe Ere Onitan Ore Mi Ti Moronmubo Martina Aderibigbe Ko
Student: Fatunmise Adewumi Abe (Project, 2025)
Department of
Ekiti State University, Ado-Ekiti, Ekiti State
Abstract
Awon Yoruba bo, won ni, "mowafoniwa ni jorejore." Iwe ere onitan "ORE MI" da lori omobinrin akekoo ile eko giga fasiti Afonja ti oruko re n je, Solayide, ti obi re ko ni owo lowo sugbon won n gbiyanju fun un. Iwa omoluwabi ni Sola wu titi ti o fi pari eko re. Nje iwa naa so eso rere fun un? Sola pade ore koriko sun kan ninu ile eko giga ti oruko re n je, Kunbi. Iwa won yato gedengbe, won si ni ife ara won. Sugbon se oko ore won gunle si ebute to dara? Kunbi dale ore, igbeyin re ko si dara.
Keywords
For the full publication, please contact the author directly at: fatunmiseadewumi@gmail.com
Filters
Institutions
- Landmark University, Omu-Aran, Kwara State 1
- Lead City University, Ibadan, Oyo State 1
- Lens Polytechnic, offa, Kwara State. 215
- Madonna University, Elele, Rivers State 20
- Madonna University, Okija, Anambra State 2
- Mcpherson University, Seriki Sotayo, Ogun State 1
- Michael and Cecilia Ibru University, Owhrode, Delta State 1
- Michael Okpara University of Agriculture, Umudike 43
- Michael Otedola Col of Primary Educ. Epe, Lagos (affl To University of Ibadan) 8
- Modibbo Adama University, Yola, Adamawa State 15