Atupale Iwe Ere Onitan Ore Mi Ti Moronmubo Martina Aderibigbe Ko
Student: Fatunmise Adewumi Abe (Project, 2025)
Department of
Ekiti State University, Ado-Ekiti, Ekiti State
Abstract
Awon Yoruba bo, won ni, "mowafoniwa ni jorejore." Iwe ere onitan "ORE MI" da lori omobinrin akekoo ile eko giga fasiti Afonja ti oruko re n je, Solayide, ti obi re ko ni owo lowo sugbon won n gbiyanju fun un. Iwa omoluwabi ni Sola wu titi ti o fi pari eko re. Nje iwa naa so eso rere fun un? Sola pade ore koriko sun kan ninu ile eko giga ti oruko re n je, Kunbi. Iwa won yato gedengbe, won si ni ife ara won. Sugbon se oko ore won gunle si ebute to dara? Kunbi dale ore, igbeyin re ko si dara.
Keywords
For the full publication, please contact the author directly at: fatunmiseadewumi@gmail.com
Filters
Institutions
- UMA UKPAI SCHOOL OF THEOLOGY, UYO, AKWA IBOM STATE (AFFL TO UNIVERSITY OF UYO) 1
- Umaru Ali Shinkafi Polytechnic, Sokoto, Sokoto State 24
- Umaru Musa Yaradua University, Katsina, Katsina State 28
- Umca, Ilorin (Affiliated To University of Ibadan), Kwara State 1
- University of Abuja, Abuja, Fct 117
- University of Africa, Toru-Orua, Bayelsa State 4
- University of Benin, Benin City, Edo State 362
- University of Calabar Teaching Hospital School of Health Information Mgt. 1
- University of Calabar, Calabar, Cross River State 240
- University of Ibadan, Ibadan, Oyo State 14