Atupale Iwe Ere Onitan Ore Mi Ti Moronmubo Martina Aderibigbe Ko
Student: Fatunmise Adewumi Abe (Project, 2025)
Department of
Ekiti State University, Ado-Ekiti, Ekiti State
Abstract
Awon Yoruba bo, won ni, "mowafoniwa ni jorejore." Iwe ere onitan "ORE MI" da lori omobinrin akekoo ile eko giga fasiti Afonja ti oruko re n je, Solayide, ti obi re ko ni owo lowo sugbon won n gbiyanju fun un. Iwa omoluwabi ni Sola wu titi ti o fi pari eko re. Nje iwa naa so eso rere fun un? Sola pade ore koriko sun kan ninu ile eko giga ti oruko re n je, Kunbi. Iwa won yato gedengbe, won si ni ife ara won. Sugbon se oko ore won gunle si ebute to dara? Kunbi dale ore, igbeyin re ko si dara.
Keywords
For the full publication, please contact the author directly at: fatunmiseadewumi@gmail.com
Filters
Institutions
- Federal Polytechnic Ede, Osun State 38
- Federal Polytechnic, Ado-Ekiti, Ekiti State 29
- Federal Polytechnic, Bauchi, Bauchi State 3
- Federal Polytechnic, Bida, Niger State 15
- Federal Polytechnic, Damaturu, Yobe State 11
- Federal Polytechnic, Ede, Osun State 135
- Federal Polytechnic, Idah, Kogi State 1
- Federal Polytechnic, Ilaro, Ogun State 11
- Federal Polytechnic, Ile-Oluji, Ondo State 7
- Federal Polytechnic, Kaura/Namoda, Zamfara State 3