Atupale Iwe Ere Onitan Ore Mi Ti Moronmubo Martina Aderibigbe Ko
Student: Fatunmise Adewumi Abe (Project, 2025)
Department of
Ekiti State University, Ado-Ekiti, Ekiti State
Abstract
Awon Yoruba bo, won ni, "mowafoniwa ni jorejore." Iwe ere onitan "ORE MI" da lori omobinrin akekoo ile eko giga fasiti Afonja ti oruko re n je, Solayide, ti obi re ko ni owo lowo sugbon won n gbiyanju fun un. Iwa omoluwabi ni Sola wu titi ti o fi pari eko re. Nje iwa naa so eso rere fun un? Sola pade ore koriko sun kan ninu ile eko giga ti oruko re n je, Kunbi. Iwa won yato gedengbe, won si ni ife ara won. Sugbon se oko ore won gunle si ebute to dara? Kunbi dale ore, igbeyin re ko si dara.
Keywords
For the full publication, please contact the author directly at: fatunmiseadewumi@gmail.com
Filters
Institutions
- Osun State College of Education, Ila-Orangun(Aff To Ekiti State Uni), Osun State 1
- Osun State College of Education, Ilesa, Osun State. (affl To Univ of Ibadan) 2
- Osun State Polytechnic, Iree, Osun State 467
- Osun State University, Osogbo, Osun State 11
- Our Saviour Institute of Science and Technology (polytechnic) Enugu, Enugu State 1
- PAN-ATLANTIC UNIVERSITY, KM 52 LEKKI-EPE EXPRESSWAY, IBEJU-LEKKI, LAGOS STATE. 14
- Paul University, Awka, Anambra State 2
- Petroleum Training Institute, Effurun, Delta State 1
- Precious Cornerstone University, Ibadan, Oyo State 1
- Prince Abubakar Audu University, Anyigba 30