Atupale Iwe Ere Onitan Ore Mi Ti Moronmubo Martina Aderibigbe Ko
Student: Fatunmise Adewumi Abe (Project, 2025)
Department of
Ekiti State University, Ado-Ekiti, Ekiti State
Abstract
Awon Yoruba bo, won ni, "mowafoniwa ni jorejore." Iwe ere onitan "ORE MI" da lori omobinrin akekoo ile eko giga fasiti Afonja ti oruko re n je, Solayide, ti obi re ko ni owo lowo sugbon won n gbiyanju fun un. Iwa omoluwabi ni Sola wu titi ti o fi pari eko re. Nje iwa naa so eso rere fun un? Sola pade ore koriko sun kan ninu ile eko giga ti oruko re n je, Kunbi. Iwa won yato gedengbe, won si ni ife ara won. Sugbon se oko ore won gunle si ebute to dara? Kunbi dale ore, igbeyin re ko si dara.
Keywords
For the full publication, please contact the author directly at: fatunmiseadewumi@gmail.com
Filters
Institutions
- HASSAN USMAN KATSINA POLYTECHNIC (NCE), KATSINA, KATSINA STATE 4
- Hassan Usman Katsina Polytechnic, Katsina, Katsina State 5
- Heritage Polytechnic, Ikot Udota, Akwa Ibom State 46
- Hussaini Adamu Federal Polytechnic, Kazaure, Jigawa State 8
- Ibrahim Badamasi Babangida University, Lapai, Niger State 24
- Igbinedion University, Okada, Benin City, Edo State 2
- Ignatius Ajuru University of Education, Port Harcourt, Rivers State 8
- Imo State Polytechnic, Umuagwo, Owerri, Imo State 3
- Imo State University, Owerri, Imo State 45
- Institute of Management and Technology, Enugu, Enugu State 11