Atupale Iwe Ere Onitan Ore Mi Ti Moronmubo Martina Aderibigbe Ko
Student: Fatunmise Adewumi Abe (Project, 2025)
Department of
Ekiti State University, Ado-Ekiti, Ekiti State
Abstract
Awon Yoruba bo, won ni, "mowafoniwa ni jorejore." Iwe ere onitan "ORE MI" da lori omobinrin akekoo ile eko giga fasiti Afonja ti oruko re n je, Solayide, ti obi re ko ni owo lowo sugbon won n gbiyanju fun un. Iwa omoluwabi ni Sola wu titi ti o fi pari eko re. Nje iwa naa so eso rere fun un? Sola pade ore koriko sun kan ninu ile eko giga ti oruko re n je, Kunbi. Iwa won yato gedengbe, won si ni ife ara won. Sugbon se oko ore won gunle si ebute to dara? Kunbi dale ore, igbeyin re ko si dara.
Keywords
For the full publication, please contact the author directly at: fatunmiseadewumi@gmail.com
Filters
Institutions
- Federal University, Lokoja, Kogi State 1
- Federal University, Otuoke, Bayelsa State 20
- Federal University, Wukari, Taraba State 5
- Fidei Polytechnic, Gboko, Benue State 1
- First Technical University, Ibadan, Oyo State 2
- Fountain University, Osogbo, Osun State 20
- Gateway Ict Polytechnic, Saapade, Ogun State 9
- Godfrey Okoye University, Urgwuomu- Nike, Enugu State 4
- Gombe State University, Tudun Wada, Gombe, Gombe State 18
- Hallmark University, Ijebu-Itele,ogun State 1