Atupale Iwe Ere Onitan Ore Mi Ti Moronmubo Martina Aderibigbe Ko
Student: Fatunmise Adewumi Abe (Project, 2025)
Department of
Ekiti State University, Ado-Ekiti, Ekiti State
Abstract
Awon Yoruba bo, won ni, "mowafoniwa ni jorejore." Iwe ere onitan "ORE MI" da lori omobinrin akekoo ile eko giga fasiti Afonja ti oruko re n je, Solayide, ti obi re ko ni owo lowo sugbon won n gbiyanju fun un. Iwa omoluwabi ni Sola wu titi ti o fi pari eko re. Nje iwa naa so eso rere fun un? Sola pade ore koriko sun kan ninu ile eko giga ti oruko re n je, Kunbi. Iwa won yato gedengbe, won si ni ife ara won. Sugbon se oko ore won gunle si ebute to dara? Kunbi dale ore, igbeyin re ko si dara.
Keywords
For the full publication, please contact the author directly at: fatunmiseadewumi@gmail.com
Filters
Institutions
- Mohammed Lawan College of Agriculture, Maiduguri, Borno State 12
- Moshood Abiola Polytechnic, Abeokuta, Ogun State 7
- Nasarawa State University, Keffi, Nasarawa State 8
- Niger Delta University, Wilberforce Island, Bayelsa State 28
- Niger State College of Education, Minna, (Affl To Usmanu Danfodiyo Uni, Sokoto) 1
- Nigeria Maritime University, Okerenkoko, Delta State 1
- Nigerian Army University, Biu, Borno State 3
- Nile University of Nigeria, Abuja 3
- Nnamdi Azikiwe University, Awka, Anambra State 98
- Northwest University, Kano, Kano State 179